Lewati ke konten utama
Lirik lagu

Aanu Ni

BisiManuel

Ohun t’awon kan gbawe fun
Lo se were
Omi ti won ni ko le san

To wa di ibu
Mo ni bo se n s'ola re o
Oun loye

Anu ni o
A se iru emi le joba
Owi ninu oro re, mo gba be

A se ireti tun wa fun gi agelori
O boro re mu, mo gba be
Omi odo to kan d'ele pada dun

Gege bi oro re, mo gba be
Anu ni
Ohun t’awon kan gbawe fun

Lo se were
Omi ti won ni ko le san
To wa di ibu

Mo ni bo se n s'ola re o
Oun loye
Anu ni

T’oba je ile mo ti wa
Ko le kan mi
Won ni no be hin turn

Owo yen so wipe kan gbe fun mi
Ere asapojude ti gbogbo won sa de fori mi
Aide mo wa wu mi o ku da ise olorun duro

Ko da ise olorun duro o
I was barely whispering Your name
Didn’t even know the words to say

But somehow doors just opened up for me
Like You were waiting where I’d be
And I don’t understand it

Thats the flavour of mercy
Ohun t’awon kan gbawe fun
Lo se were

Omi ti won ni ko le san
To wa di ibu
Mo ni bo se n s'ola re o

Oun loye
Anu ni